Ísíkẹ́lì 37:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú mi lọ síwájú àti sẹ́yìn láàrin wọn, èmi sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn egungun ní orí ilẹ̀ àfonífojì, àwọn egungun tí ó gbẹ gan.

Ísíkẹ́lì 37

Ísíkẹ́lì 37:1-4