Ísíkẹ́lì 36:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó pọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ bí ọ̀wọ́ ẹran fún ìrúbọ ní Jérúsálẹ́mù ní àsìkò àjọ. Ìlú ti a parun yóò wá kún fún agbo àwọn ènìyàn. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa.”

Ísíkẹ́lì 36

Ísíkẹ́lì 36:34-38