Ísíkẹ́lì 34:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nítorí náà, èyí yìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí fún wọn: Wòó, èmi fúnra mi yóò ṣe ìdájọ́ láàárin àgùntàn tí ó sanra àti èyí tí ó rù.

Ísíkẹ́lì 34

Ísíkẹ́lì 34:19-21