Ísíkẹ́lì 34:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé dandan ni kí agbo ẹran mi jẹ́ koríko tí ẹ ti tẹ̀ mọ́lẹ̀, kí wọn sì mú omi tí wọ́n ti fi ẹsẹ̀ wọn sọ di ẹrẹ̀?

Ísíkẹ́lì 34

Ísíkẹ́lì 34:11-23