Ísíkẹ́lì 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kò rán ọ sí àwọn tó ń sọ èdè àjèjì tàbí tí èdè wọn ṣòro láti gbọ́, ṣùgbọ́n orílẹ̀ èdè Ísírẹ́lì ni mo rán ọ sí

Ísíkẹ́lì 3

Ísíkẹ́lì 3:1-7