Ísíkẹ́lì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kì í ṣe sí ọ̀pọ̀ ènìyàn tó ń sọ àjèjì èdè tàbí tí èdè wọn ṣòro láti gbọ́, àwọn tí ọ̀rọ̀ wọn le fún ọ láti gbọ́ yé. Dájúdájú bí mo bá rán ọ sí wọn, wọn ì bá sì fetí sílẹ̀ sí ọ.

Ísíkẹ́lì 3

Ísíkẹ́lì 3:1-8