Ísíkẹ́lì 27:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Júdà àti Ísírẹ́lì, àwọn ni oníṣòwò rẹ; wọn ṣe ìpààrọ̀ ọkà, Mínnítì, àkàrà àdídùn; pannági, oyin, epo àti ìpara olóòórùn dídùn ni wọ́n fi ná ọjà rẹ.

Ísíkẹ́lì 27

Ísíkẹ́lì 27:16-21