Ísíkẹ́lì 27:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Dámásíkù, ni oníṣòwò rẹ, nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ọjà tí ó ṣe àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọrọ̀; ní ti ọtí wáìnì tí Helíbónì, àti irun àgùntàn funfun.

Ísíkẹ́lì 27

Ísíkẹ́lì 27:12-27