Ísíkẹ́lì 23:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kò fi ìwa aṣẹ́wó tí ó ti bẹ̀rẹ̀, ni Éjíbítì sílẹ̀, ní ìgbà èwe rẹ̀ àwọn ọkùnrin n bá a sùn, wọn fi ọwọ́ pa àyà èwe rẹ̀ lára wọn sì ń ṣe ìfẹ́kúùfẹ́ sí i.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:5-10