Ísíkẹ́lì 23:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O fi ara rẹ̀ fún gbajúmọ̀ ọkùnrin Ásíríà gẹ́gẹ́ bí pansága obìnrin, o fi òrìsà gbogbo àwọn tí ó ní ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ sí i sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́,

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:3-9