Ísíkẹ́lì 23:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń fojúsọ́nà sí àìlófin ìgbà èwe rẹ̀ ni Éjíbítì, nìgbà tí wọ́n fi ọwọ́ pa igbáàyà rẹ̀ àti ọmú ìgbà èwe rẹ̀.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:13-31