Ísíkẹ́lì 23:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, Óhólíbà, báyìí ní Olúwa Olódùmarè wí: Èmi yóò gbé olólùfẹ́ rẹ dìde sí ọ, àwọn tí o kẹ́yìn si ní ìtìjú, èmi yóò sì mú wọn dojú kọ ọ́ ní gbogbo ọ̀nà

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:20-31