Ísíkẹ́lì 23:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀ ni ó ti ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ sí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀, tí àwọn tí ǹnkan ọkùnrin wọn dàbí ti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àwọn ẹni tí ìtíjáde ara wọn dàbí ti àwọn ẹṣin.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:19-25