Ísíkẹ́lì 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì gbọ́ ariwo ìyẹ́ àwọn kérúbù yìí títí dé àgbàlá tó wà níta gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí Ọlọ́run Olódùmáre bá ń sọ̀rọ̀.

Ísíkẹ́lì 10

Ísíkẹ́lì 10:4-12