Ísíkẹ́lì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Olúwa pàṣẹ fún ọkùnrin aláṣọ funfun yìí pé, “Mú iná láàrin àwọn kẹ̀kẹ́, láàrin àwọn kérúbù,” ó sì lọ dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn kẹ̀kẹ́ náà.

Ísíkẹ́lì 10

Ísíkẹ́lì 10:1-10