Ìfihàn 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì gbọ́ iye àwọn tí a fi èdìdì sàmì si: Àwọn tí a sàmì sí jẹ́ ọ̀kẹ́ méje o lé ẹgbàájì láti inú gbogbo ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá.

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:2-13