Ìfihàn 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú ẹ̀yà Júdà a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.Láti inú ẹ̀yà Reubẹ́nì a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.Láti inú ẹ̀yà Gádì a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:1-9