Ìfihàn 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wí pé, “Ẹ má ṣe pa ayé, tàbí òkun, tàbí igi lára, títí àwa ó fi fi èdìdì sàmì sí àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run wa ní iwájú wọn.”

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:1-10