Ìfihàn 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéfín ìdálóró wọn ń lọ sókè títí láéláé wọn kò sì ní ìsinmi ni ọ̀sán àti ní òru, àwọn tí ń foríbalẹ̀ fún ẹranko náà àti fún àwòrán rẹ̀, àti ẹnikẹ́ni tí o ba sì gba àmì orúkọ rẹ̀.”

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:4-18