Ìfihàn 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nihìn-ín ni sùúrù àwọn ènìyàn mímọ́ gbé wà: àwọn tí ń pa òfin Ọlọ́run àti ìgbàgbọ́ Jésù mọ́.

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:7-20