Ìfihàn 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹranko tí mo rí náà sì dàbí ẹkùn, ẹsẹ̀ rẹ̀ sì dàbí tí béárì ẹnu rẹ̀ sì dàbí tí kìnnìún: dírágónì náà sì fún un ni agbára rẹ̀, àti ìtẹ́ rẹ̀, àti àṣẹ ńlá.

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:1-8