Ìfihàn 13:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì rí ẹranko kan ń ti inú òkun jáde wá, ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá, lórí àwọn ìwo náà ni orúkọ ọ̀rọ̀-òdì wà.

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:1-2