Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fílípì sì wí pé, “Bí ìwọ bá gbàgbọ́ tọkàntọkàn, a lè bamitíìsì rẹ.” Ìwẹ̀fà náà sì dáhùn pé, “Mo gbàgbọ́ pé Jésù Kírísítì Ọmọ Ọlọ́run ni.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:31-40