Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì pàṣẹ kí kẹ̀kẹ́ dúró jẹ́; àwọn méjèèjì Fílípì àti Ìwẹ̀fà sì sọ̀kalẹ̀ lọ sínú omi, Fílípì sì bamitíìsì rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:37-40