Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n sì tí ń lọ lọ́nà, wọ́n dé ibi omi kan; ìwẹ̀fà náà sì wí pé, “Wò ó, omi nìyí. Kín ni ó dá mi dúró láti bamitíìsì?”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:32-40