Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fílípì sí ya ẹnu rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ láti ibi ìwé-mímọ́ yìí, ó sí wàásù ìyìn rere ti Jésù fún un.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:32-40