Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì gbé òkú wọn padà wá sí Ṣékémù, a sì tẹ́ wọn sínú ibojì ti Ábúráhámù rà ni ọwọ́ àwọn ọmọ Ámórì ní Sékémù ní iye-owó wúrà kan.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:9-22