Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jákọ́bù sọ̀kalẹ̀ lọ sí Íjíbítì, ní ibi tí òun àti àwọn baba wa kú sí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:11-22