Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí àkókò tí Ọlọ́run yóò mú ìlérí tí ó ṣe fún Ábúráhámù sẹ kù dẹ̀dẹ̀, àwọn ènìyàn wa ń gbérù si gidigidi ní iye ní ilẹ̀ Íjíbítì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:12-26