Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì fi í lélẹ̀ lẹ́ṣẹ̀ àwọn àpósítélì, wọn sì ń pín fún olukúlúkù gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe aláìní sí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:26-37