Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí kò sí ẹnìkan nínú wọn tí ó ṣe aláìní, nítorí iye àwọn tí ó ní ilẹ̀ tàbí ilé tà wọ́n, wọ́n sì mú owó ohun tí wọn tà wá.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:33-37