Àti Jóṣéfù, tí a ti ọwọ́ àwọn àpósítélì sọ àpèlé rẹ̀ ní Bánábà (ìtúmọ̀ èyí tí ń jẹ Ọmọ-Ìtùnú), ẹ̀yà Léfì, àti ará Sáípúrọ́sì.