Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ṣíṣe nǹkan wọ̀nyí, wọ́n rí mí nínú iyẹ̀wù tẹ́ḿpílì, bí mo ti ń parí ètò ìwẹ́nú, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe ní àárin àwùjọ ènìyàn, tàbí pẹ̀lú ariwo.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:12-20