Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ọdun púpọ̀, mo wá sí Jerúsálẹ́mù láti mu ẹ̀bún wá fún àwọn ẹ̀nìyàn mi fún aláìní àti láti fi ọrẹ lélẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:10-18