Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kejì wọ́n sì fi àwọn ẹlẹ́ṣin sílẹ̀ láti máa bá a lọ, àwọn sì padà wá sínú àgọ́ àwọn ológun.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:29-33