Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n dé Kesaríà, tí wọ́n sí fi ìwé fún baalẹ́, wọ́n mú Pọ́ọ̀lù pẹ̀lú wá ṣíwájú rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:24-35