Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn ọmọ-ogun gba Pọ́ọ̀lù, wọ́n sì mú un lóru lọ si Áńtírípátírì, gẹ́gẹ́ bí a tí pàṣẹ fún wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:29-35