Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí mo sì ń fẹ́ mọ ìdí ọ̀ràn tí wọn fi ẹ̀sùn kàn án sí, mo mú un sọ̀kalẹ̀ lọ sí àjọ ìgbìmọ̀ wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:25-29