Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí mo rí pé, wọ́n fisùn nítorí ọ̀ràn òfin wọn, bẹ́ẹ̀ ni kò dá ọ̀ràn ohun kan tí ó tọ́ sí ikú àti sí ẹ̀wọ̀n.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:19-30