Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọkùnrin kan tí a ń pè ní Ananáyà tọ̀ mí wá, ẹni tó jẹ́ olùfọkànṣìn ti òfin, tí ó sì lórúkọ rere lọ́dọ̀ gbogbo àwọn Júù tí ó ń gbé ibẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:8-13