Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dúró tì mí, ó sì wí fún mi pé, ‘Arákùnrin Ṣọ́ọ̀lù, gba ìríran!’ Ní ẹsẹ̀ kan náà, mo sì sí ojú sí òkè mo sì lè rí i.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:10-16