Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ẹ máa sọ́ra, ki ẹ sì máa rántí pé, fún ọdún mẹ́ta, èmi kò dẹ́kun láti máa fi omijé kìlọ̀ fún olúkúlùkù ní ọ̀sán àti ní òru.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:24-38