Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ǹjẹ́ nísinsìn yìí, ará, mo fi yín lé Ọlọ́run lọ́wọ́ àti ọ̀rọ̀ oore-ọfẹ́ rẹ̀, tí ó lè gbé yín dúró, tí ó sì lè fún yín ní ìní láàrin gbogbo àwọn tí a sọ di mímọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:28-38