Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí èmi mọ̀ pé, lẹ́yìn lílọ̀ mi, ìkookò búburú yóò wọ àárin yín, yóò sì tú agbo ká.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:26-35