Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kíyèsára yin, àti sí gbogbo agbo tí Ẹ̀mí Mímọ́ fi yín ṣe alábòójútó rẹ̀, láti máa tọ́jú ìjọ Ọlọ́run, tí ó tí fi ẹ̀jẹ̀ (ọmọ) rẹ̀ rà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:27-36