Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì dúró ṣinṣin nínú ẹ̀kọ́ àwọn àpósítélì, àti ní ìdàpọ̀, ní bíbu àkàrà àti nínú àdúrà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:34-47