Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà àwọn tí ó fi ayọ̀ gba ọ̀rọ̀ rẹ̀ a bamítíìsì wọn, lọ́jọ́ náà a sì kà ìwọn ẹgbẹ̀rùn mẹ́ta ọkàn kún wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:38-47