Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀rù sí ba gbogbo ọkàn; iṣẹ́ ìyanu àti iṣẹ́ àmì púpọ̀ ni a ti ọwọ́ àwọn àpósítélì ṣe.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:38-47