Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú ọ̀rọ̀ púpọ̀ mìíràn ni ó fi ń kìlọ̀ tí ó sì ń fi ń rọ̀ wọ́n wí pé, “Ẹ gba ara yín là lọ́wọ́ ìran àrékérekè yìí.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:30-47