Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí fún yín ni ìlérí náà, àti fún àwọn ọmọ yín, àti fún gbogbo àwọn tí ó jìnnà réré, àní gbogbo àwọn tí Olúwa Ọlọ́run wa yóò pè.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:35-43